Audio player
Eko nipa Odun Itunu Aawe (Video - Yoruba)
11.9 MB
Eko nipa Odun Itunu Aawe (Video - Yoruba)
Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi laruge. Ojise Olohun si pase wipe ki gbogbo Musulumi jade lo si aaye ikirun fun odun yii.
Contributors
AuthorsAbdur Rosheed Abdul Jabaar (Buwaeb)
ReviewersRafiu Adisa Bello
Download all material files
2 files • 49 MB
Material files
1 / 2Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎬 Eko nipa Odun Itunu Aawe (Yoruba)
📝 Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi laruge. Ojise Olohun si pase wipe ki gbogbo Musulumi jade lo si aaye ikirun fun odun yii.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/videos/448380