Audio player
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Audio - Yoruba)
27.1 MB
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Audio - Yoruba)
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/829543