Audio player
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ (Audio - Yoruba)
27.3 MB
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ (Audio - Yoruba)
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
2 files • 54 MB
Material files
Series playlist1 / 2About 54 MBShowing 1-2 of 2
CSV file for the full series
Downloads 2 records with direct source file URLs, estimated at 54 MB.
Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ (Yoruba)
📝 1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/812022