Audio player
Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah (Audio - Yoruba)
26.3 MB
Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah (Audio - Yoruba)
Koko ibanisọrọ yii ni: (i) Itumọ atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun (ii) Awọn ọna ti a ngba se atẹgun lati wa oore ni ọdọ Ọlọhun. (iii) Awọn gbolohun ti o lẹtọ ti Musulumi fi le se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/812018