Audio player
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku (Audio - Yoruba)
26.9 MB
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku (Audio - Yoruba)
1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un. 2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se nigbati o ba npọkaka iku. 3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ ki a se nigba ti oku ba ku tan.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
3 files • 81 MB
Material files
Series playlist1 / 3About 81 MBShowing 1-3 of 3
CSV file for the full series
Downloads 3 records with direct source file URLs, estimated at 81 MB.
Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku (Yoruba)
📝 1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un. 2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se nigbati o ba npọkaka iku. 3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ ki a se nigba ti oku ba ku tan.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/805618