Audio player
Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu (Audio - Yoruba)
26.6 MB
Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu (Audio - Yoruba)
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
2 files • 51 MB
Material files
Series playlist1 / 2About 51 MBShowing 1-2 of 2
CSV file for the full series
Downloads 2 records with direct source file URLs, estimated at 51 MB.
Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu (Yoruba)
📝 1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/805550