Audio player
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a) (Audio - Yoruba)
25.8 MB
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a) (Audio - Yoruba)
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye. 2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi? 3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii: - Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si? - Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni? - Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ? - Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
3 files • 77 MB
Material files
Series playlist1 / 3About 77 MBShowing 1-3 of 3
CSV file for the full series
Downloads 3 records with direct source file URLs, estimated at 77 MB.
Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a) (Yoruba)
📝 1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye. 2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi? 3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii: - Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si? - Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni? - Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ? - Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/803817