Audio player
Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki (Audio - Yoruba)
24.7 MB
Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki (Audio - Yoruba)
Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/794733