Audio player
Iwọ Aladugbo (Audio - Yoruba)
26 MB
Iwọ Aladugbo (Audio - Yoruba)
1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ. 2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
2 files • 52 MB
Material files
Series playlist1 / 2About 52 MBShowing 1-2 of 2
CSV file for the full series
Downloads 2 records with direct source file URLs, estimated at 52 MB.
Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Iwọ Aladugbo (Yoruba)
📝 1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ. 2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/794620