Audio player
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna (Audio - Yoruba)
26.07 MB
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna (Audio - Yoruba)
Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
Contributors
AuthorsRafiu Adisa BelloAbdur - rahman Adunola Abdul - wahab
ReviewersRafiu Adisa Bello
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna (Yoruba)
📝 Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/450247