Reader ready.
Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ (Article - Yoruba)
Akosile yi so oro lori ohun ti a npe ni wiwa alubarika bi awon onimimo se se alaye re, leyinnaa o so nipa awon ipin wiwa alubarika eyi ti o pin si meji: eyi ti o leto ati eyi ti ko leto ti oro si tun waye lori awon nkan ti Olohun fi alubarika si ara won ti o si se e leto lati fi won wa alubarika.
Contributors
AuthorsRafiu Adisa Bello
ReviewersHamid Yusuf
Download all material files
2 files • 2.9 MB
Material files
1 / 2Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
📄 Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/articles/794258