Reader ready.
Brief Presentation on Islam (Article - Yoruba)
This is an article in Yoruba gives a brief presentation on Islam.
Contributors
AuthorsScientific Research Admission of Islamic University , Madinah Munawara
Sourcesiu - The Islamic University Website in Almadinah Almunawara
Download all material files
2 files • 739 KB
Material files
1 / 2Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
📄 ALAYE NIPA ESIN ISLAAM NISOKI (Yoruba)
📝 تعريف موجز بالإسلام بلغة : اليوربا Introduction to Islam in Yoroba Language Ni Oruko Olohun Oba Ajoke aye Asake orun. ALAYE NIPA ESIN ISLAAM NISOKI. Gbogbo eyin je ti Olohun, Eni ti I se Oba gbogbo aye. Ki ike ati ola si ma a je ti asiwaju gbogbo awon ojise Anabi wa Muhammad ati awon ara ile re pelu awon alabarin (sohaabah) re ni apapo. Lehin - wa igba - naa, esin ISLAM: ohun ni ki eniyan jeri pe kosi enikankan toye kasin ayafi Olohun, ati wipe Anabi Muhammad ojise Olohun ni. Pelu okan ati ahan, ati awon orikerike ara. Esin ti anwiyi ko awon origun igbagbo mefeefa sinu, ati lilo awon origun Islam maraarun, ati mima se daada. Osije ipari awon ise Oloun ti osokale fun olupinnu awon Anabi ati ojise, eleyi tii se Anabi Muhammad omo Abdullah (ki ike ati ola Olohun o maa baa) . Oun si ni esin otito ti esin miran ki yo o je atewogba ni odo Olohun yato si oun nikan. Olohun si ti se e ni esin irorun ti ko si isoro kankan tabi wahala nibe. Ko se ohun ti o koja ikapa won ni oranyan fun awon ti won gba esin naa. Beeni ko si la ohun ti o koja agbara won kowon ni orun. Ohun sini esin ti ose pe imo Oloun ni okan (al - Taoheed) ni ipilese re, ami re si ni ododo, abalo-ababo re si ni deede, opomulero re si ni otito, emi re si ni ike. Oun si ni esin ti o tobi ti o se pe oun dari gbogbo eda si ibi gbogbo ohun ti yo o je anfaani fun won ni orun won ati aye won. Bee naa ni o si tun n ki won ni ilo nipa gbogbo ohun ti yo o se won ni suta ni isemi orun ati ni igbesi aye won. Ohun ni esin ti Olohun fi se atunse awon adi-okan ati awon iwa. Ohun naa ni O fi se atunse isemi aye ati ti orun. Ohun ni Olohun fi se irepo laarin awon okan ti o keyin si ara won, ati awon ife inu oniranran. Nipase eyi ni O fi yoo ninu okunkun biribiri iro, ti O si se ifinimona re lo si ibi otito, ti O si to si ona toto. ISLAM ni esin ti o duro to, eyi ti a gbe kale ni ona ti o dara de opin ninu gbogbo awon iro ti o muwa ati ninu gbogbo awon idajo re pata. Ko si iroyin kankan ninu re ayafi otito ati ododo be e si ni ko se idajo kankan ayafi pelu daada ati deede. Ninu re ni: awon adisokan ti o ni alaafia, awon ise ti o duro to, awon iwa ti o dara pari, ati awon eko ti o ye kooro. Ni soki, ise ISLAM wa lati se amulo awon ohun ti o n bo wonyii: (1) Sise alaye Olohun ti I se oluda awon eniyan fun won pelu (ifosiwewe alaye) awon oruko Re ti o dara julo eyi ti kosi oloruko fun ati awon iroyin Re ti o ga pari, eyiti kosi alafiwe fun nibe, pelu awon ise Re ti o mu ogbon dani ti kosi ni orogun nibe,ati awon ohun ti o to si Olohun nikan soso. (2) Pipe awon eru Olohun (awon eniyan) losi ibi jijosin fun Olohun nikan soso ti kosi orogun fun. Eyi yo o je be e nipa sise ohun ti Olohun se lofin fun won ninu tira re (Alquran) ati ilana ojise re (sunnat) pelu sise ohun ti Olohun fe, ati jijina si ohun ti o ko. Eyi ti o se pe daradara ati orire won ni aye ati ni orun won wa ni be. (3) Riran awon eniyan leti aye won ati ibuseri padabosi won leyin iku ati ohun ti won yo o ba pade ninu saaree won ati nigba igbende won ati isiro ise won ati nile ikeyin won, ogba idera alujonaa ni yoo je, abi ina ti o n jo geregere, gbogbo re patapata ni odiwon ise onikaluku. Ni soki a lee se alaye awon origun pataki Islaam ninu awon koko ti o n bo wonyii: IKINNI: Awon origun igbagbo (Imoni) osije mefa: (1) Gbigba Olohun gbo. Eleyi si ko awon inkan ti o n bo wonyi sinu: (a) Nini igbagbo pe okan ni Olohun nibi ise e re. Eyi tumo si pe Oun ni Oba, Oluda, Oluni,Olusakoso gbogbo awon eto eda re aseyowu lori won. (b) Nini igbagbo pelu pe Olohun nikan ni Atoosin eyi tumo si pe Oun ni Olohun otito gbogbo in ti won bati n se ijosin fun leyin Olohun iro ati ikuna ni, ti koto. (d) Nini igbagbo ninu awon oruko Olohun ati awon iroyin Re. Eyi tumo si pe Oun ni o ni awon oruko ti o dara julo ati awon iroyin ti o pe perepere ti o si ga julo gege bi o ti wa ninu tira Re (Al-quran) ati (sunnat) ojise Re (ki ike ati ati ola Olohun ki o ma a baa) (2) Nini igbagbo ninu awon ironse Olohun (Molaaikat) : Awon Molaaikat je eru Olohun alaponl...
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/articles/601