Video player
Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye (Video - Yoruba)
56.73 MB
Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye (Video - Yoruba)
Olubanisoro se alaye bi ojise Olohun anabi Muhammad se je ike fun gbogbo aye, Olohun lo ojise naa lati se agbega fun awon iwa rere O si loo lati pa awon iwa buburu re. Olohun si da ojise re ni eniti o pe ni eda ati ni iwa.
Contributors
AuthorsQomorudeen YunusSaeed Jumua
ReviewersSaeed Jumua
Download all material files
2 files • 69 MB
Material files
1 / 2Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎬 Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/videos/450665