Reader ready.
Awọn isę Hajj (Poster - Yoruba)
Awọn ise Hajj: Aworan ti a ṣe ni ede Yoruba, ti Sheikh Dr. Haitham Sarhan pese re, o ṣe alaye gbogbo ohun ti alalaji nilo, ni ipele ipele, ati ni ọna ti o dara ati ṣoki, ti o ṣe apejuwe pẹlu awọn aworan ati awọn aami, ki a le se ise orayan nla yii gege bi Anabi Muhammad se se e, ki ike ati ola Olohun maa ba, Eniti o so pe: E gba awon ise Hajji yin lowo mi.
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🖼️ Awọn isę Hajj (Yoruba)
📝 Awọn ise Hajj: Aworan ti a ṣe ni ede Yoruba, ti Sheikh Dr. Haitham Sarhan pese re, o ṣe alaye gbogbo ohun ti alalaji nilo, ni ipele ipele, ati ni ọna ti o dara ati ṣoki, ti o ṣe apejuwe pẹlu awọn aworan ati awọn aami, ki a le se ise orayan nla yii gege bi Anabi Muhammad se se e, ki ike ati ola Olohun maa ba, Eniti o so pe: E gba awon ise Hajji yin lowo mi.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/posters/2837034