Reader ready.
The Daily Traditions and Supplications of the Prophet (Peace Be upon Him) (Book - Yoruba)
A book in Yoruba in which the author complied the daily traditions and deeds of the Prophet (peace be upon him) from waking up in the morning until sleeping at night.
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
📘 Àwọn Sunnah Ànábì Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ (Yoruba)
📝 Mó ń gbé síwájú rẹ, ìrẹ ọmọ-ìyá mi nínú ẹ̀sìn Islām, tí ó ń ka ìwé yìí; àwọn ìlànà Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ láti ìgbà tí ó bá ti jí, títí di ìgbà tí yóò sùn, èyí tí a tò ní ìbámu sí àsìkò wọn, lẹ́yìn náà máa fi àwọn ìlànà Ànábì mìíràn tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́, èyí tí kò ní àsìkò kan pàtó, tẹ̀lé e.
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/books/2828243