Audio player
Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Audio - Yoruba)
27 MB
Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Audio - Yoruba)
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.
Contributors
AuthorsAbdur Rahman Muhammadul Awwal
ReviewersHamid Yusuf
Material files
1 / 1Social-friendly share text
Inu mi dun lati pin eyi pẹlu rẹ:
🎧 Diẹ ninu awọn iwọ Ojise Ọlọhun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] (Yoruba)
🔗 https://b.islamhouse.com/yo/audios/2786389